Jump to content

Ìwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNU

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
GNU Free Documentation License
Àmí ilé-iṣẹ́ GNU, gnu
OlùdákọFree Software Foundation
Àtẹ̀jáde1.3
Atẹ̀wéjádeFree Software Foundation, Inc.
Títẹ̀jádeÀtẹ̀jáde lọ́wọ́:
3 Oṣù Kọkànlá, odún 2008
Bíbámu mọ́ DFSGBẹ́ẹ̀ni, láìsí abala kankan tó yàtọ̀
Atòlànà kọ̀mpútà ọ̀fẹ́Bẹ́ẹ̀ni
Bíbámu mọ́ GPLBẹ́ẹ̀kọ́
CopyleftBẹ́ẹ̀ni

GNU Free Documentation License (GFDL) (Ìwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNU) jẹ́ ìwé àṣẹ copyleft fún aṣàlàyé ọ̀fẹ́ látọwọ́ Free Software Foundation (FSF) fún àwọn iṣẹ́ ọwọ́ GNU. Àtẹ̀jáde 1.3 ni ó wà lọ́wọ́, ìkọ oníbiṣẹ́ rẹ̀ ṣe é rí ní àdírẹ́sì http://www.gnu.org/copyleft/fdl.html.

Ìwé àṣẹ náà wà fún aṣàlàyé atòlànà kọ̀mpútà àti bákanáà fún àwọn ìjésì míràn àti fún àwọn ìwé ìlànà. Èyí mudájú pé àwòkọ kọ̀ọ̀kan èlò náà, bótilẹ̀jẹ́ láláàtúnṣe, yíò ní ìwé àṣẹ kannáà. Àwọn àwòkọ wọ̀nyí ṣe é tà, sùgbọ́n eni tó tà gbọdọ̀ mọ̀ pé elòmíràn náà lè ṣe àtúnṣe síi láì gbàṣẹ lọ́wọ́ rẹ̀. Wikipedia ni iṣẹ́ ọwọ́ tótóbijùlọ aṣàlàyé ọ̀fẹ́ tó únlo ìwé àṣẹ yìí.


Àwọn ìjápọ̀ òde

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]